Yo
Yo Rexxie on this one
Shebi tele tele, lama fo fun won wipe
K'oma wa l'oru, toripe awa ti jade
Amo ni sinyi o
Ton ba wa losan, ton ba wa loru
Awa n be ni be, awa o de le fo fun won
Toripe awa tingasa, awa o de le sa fun won
Aye yi o le o (aye yi o le)
Aye lo m'aye le (aye lo m'aye le)
Ninu aye lo ti di f'aye, aye lo m'aye le
(Aye lo m'aye le)
Aye yi o le o (aye yi o le)
Aye lo m'aye le (aye lo m'aye le)
Ninu aye lo ti di f'aye, aye lo m'aye le
O n pe oku iya yi ni (eyin le ma sin iya yin)
Oku your mother (eyin le ma sin iya yin)
Oku momsi yin (eyin le ma sin iya yin)
Oku your mama (eyin le ma sin iya yin)
Nigba tin jale
Tin mi o ba teni kan je, ti mo ni ti're ma da
Wo ko n binu ori lasan
Ori ma mu won
Owo ma ba won
Ti olorun ba ti gba'dura mi, bukata mi a fu'ye
Aye yi o le o (aye yi o le)
Aye lo m'aye le (aye lo m'aye le)
Ninu aye lo ti di f'aye, aye lo m'aye le
(Aye lo m'aye le)
Aye yi o le o
Aye lo m'aye le
Ninu aye lo ti di f'aye, aye lo m'aye le
Ninu aye lo ti di f'aye, aye lo m'aye le (yo!)
Aye yi o le o
Aye lo m'aye le (yo Rexxie on this one)
Ninu aye lo ti di f'aye (yo!)
Aye lo m'aye le
Yo! Yo!
Spirimix